Font Size
Lefitiku 18:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 18:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
8 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ tàbùkù baba rẹ nípa bíbá ìyàwó baba rẹ lòpọ̀: nítorí ìhòhò baba rẹ ni.
Read full chapter
Lefitiku 20:11
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 20:11
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
11 (A)“ ‘Ẹnikẹ́ni tí ó bá bá aya baba rẹ̀ lòpọ̀ ti tàbùkù baba rẹ̀. Àwọn méjèèjì ni kí ẹ pa. Ẹ̀jẹ̀ wọn yóò wà lórí wọn.
Read full chapter
Deuteronomi 22:30
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Deuteronomi 22:30
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
30 (A)Ọkùnrin kò gbọdọ̀ fẹ́ ìyàwó baba rẹ̀; kò gbọdọ̀ sọ ìtẹ́ baba rẹ̀ di àìlọ́wọ̀.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.