Font Size
1 Kọrinti 16:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 16:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 (A)Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa kí ó wà pẹ̀lú yín!
Read full chapter
2 Kọrinti 13:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Kọrinti 13:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
14 (A)Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín.
Read full chapter
Galatia 6:18
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Galatia 6:18
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Filipi 4:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Filipi 4:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 (A)Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa, kí ó wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín. Àmín.
Read full chapter
1 Tẹsalonika 5:28
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Tẹsalonika 5:28
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
28 (A)Ki oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa, wà pẹ̀lú yín.
Read full chapter
2 Tẹsalonika 3:18
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Tẹsalonika 3:18
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
18 (A)Kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa wà pẹ̀lú yín.
Read full chapter
Ìfihàn 22:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìfihàn 22:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
21 (A)Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Olúwa kí ó wà pẹ̀lú gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́. Àmín.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.