Font Size
Matiu 21:28
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 21:28
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Òwe àwọn ọmọ méjì
28 (A)“Kí ni ẹ rò nípa eléyìí? Ọkùnrin kan ti ó ní àwọn ọmọkùnrin méjì. Ó sọ fún èyí ẹ̀gbọ́n pé, ‘Ọmọ, lọ ṣiṣẹ́ nínú ọgbà àjàrà lónìí.’
Read full chapter
Matiu 21:33
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 21:33
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Òwe àwọn ayálégbé
33 (A)“Ẹ gbọ́ òwe mìíràn: Baálé ilé kan tí ó gbin ọgbà àjàrà, ó ṣe ọgbà yìí ká, ó wá ibi ìfúntí sínú rẹ̀, ó kọ́ ilé ìṣọ́. Ó sì fi oko náà ṣe àgbàtọ́jú fún àwọn àgbẹ̀ kan, ó sì lọ sí ìrìnàjò.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.