Font Size
Matiu 26:57
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 26:57
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Níwájú Sahẹndiri
57 (A)Àwọn tí ó mú Jesu fà á lọ sí ilé Kaiafa, olórí àlùfáà, níbi ti àwọn olùkọ́ òfin àti gbogbo àwọn àgbàgbà Júù péjọ sí.
Read full chapter
Marku 14:53
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Marku 14:53
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jesu níwájú ìgbìmọ̀ Sahẹndiri
53 (A)Wọ́n mú Jesu lọ sí ilé olórí àlùfáà, gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbàgbà Júù àti àwọn olùkọ́ òfin péjọ síbẹ̀.
Read full chapter
Luku 22:54
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 22:54
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Peteru sẹ́ Jesu
54 (A)Wọ́n sì gbá a mú, wọ́n sì fà á lọ, wọ́n sì mú un wá sí ilé olórí àlùfáà. Ṣùgbọ́n Peteru tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ní òkèrè.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.